Friday, August 17, 2012

MY FAMILY EULOGY

Elegushi, Ekan Mebi
Omo Iroko lawe
Omo Olofin Ajaye
Omo Isan Arewa Ejo
Omo Elegba Meta Lopo-po
Omo Ota Meta Meji Lagbadan
Ikan L'eremi
Omo Epo Were-were
Lojude Ilasan
Won ki nfi Oko Ro
Won ki nfi Ada Ro
Bi a Ko Ba Ro
A Ko Gbodo Kuro Nibe
Omo Manu Manu
Temi Nikan ko
Omo Akenigbo
Ki Eru Ki Oba Ara Ona
Omo Apekan
Ma Fun Obirin Je
Omo Eleku Meden
Omo Imole Afeleja
Omo A Sa Ni Poriki Poriki
Omo Asa Majumu
Omo Adamu Sere
Omo Adese Mu Ye Ge